Ọ lọ run, Nibo Lo Wa? - Adeola Oreoluwa Adefeso - Books - Iem Press - 9781636031224 - November 22, 2021
In case cover and title do not match, the title is correct

Ọ lọ run, Nibo Lo Wa?

Adeola Oreoluwa Adefeso

Price
Íkr 2,479
excl. VAT

Ordered from remote warehouse

Expected delivery Aug 21 - Sep 1
Add to your iMusic wish list

Ọ lọ run, Nibo Lo Wa?

A bí Adé?lá ?r?olúwa Adéf??s?? ní ìpínl?? Ògùn ní oríl?? èdè Nàìjíríà. Ó ?e èwe r?? nínú ay?? àti ìdùnnú. Àw?n òbí r?? àgbà ní ìdílé ìyá ló t?? ? dàgbà p??lú ìf?? tó wàyàmì àti ??k?? ìwé tó yè kooro, òun náà sì dara p?? m?? ?gb?? ak?rin agbègbè ib??. ?ùgbó?n n?kan yí bìrí nígbà tí ó kó sí wàhálà ab?? ilé látàrí ìjìyà tí ó ? rí láti ??d?? ?k? r??. Inú làásìgbò ìjìyà ara àti ?kàn yìí ló wà tí ó fi pàdánù àw?n ìbejì ?kùnrin r?? méjèèjì tí ó bí ní kògbókògbó.

Nínú ?dún 2019, ?m?kùnrin r??, àbísìkejì, tí ó fìgbà kan j?? ?m? ogun ojú omi il?? Am??ríkà náà tún pa ara r??. L??yìn èyí ni Adé?lá tún rí àw?n ??r?? kòbákùngbé tí ?k? r?? k? nípa r?? sí orí ??r? ayélujára kà dé ibi pé òun lòun fa ikú ?m? àw?n ??hún.

Ìrora, ìf??, àti ìgbàgb?? Adé?lá fara hàn kedere nínú ìtàn àgb??gbárímú yìí tí ó gbé kal?? ní ìrètí pé yóò dé etígb???? àw?n tí yóò wúlò fún.

"Nínú ìwé yìí, Adé?lá gbé ìtàn akíkanjú obìnrin kan tí ó dojú k? wàhálà ab??le kal??. L??yìn-ò-r?yìn, p??lú ìrànl??w?? ?ló?run, ó jáwé olúborí." Iloh, Friday Okechukwu (Ph. D)


114 pages

Media Books     Paperback Book   (Book with soft cover and glued back)
Released November 22, 2021
ISBN13 9781636031224
Publishers Iem Press
Pages 114
Dimensions 127 × 203 × 6 mm   ·   117 g
Language Yoruba  

Show all

More by Adeola Oreoluwa Adefeso